Font Size
Johanu 3:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 3:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
31 (A)“Ẹni tí ó ti òkè wá ju gbogbo ènìyàn lọ; ẹni tí ó ti ayé wá ti ayé ni, a sì máa sọ ohun ti ayé. Ẹni tí ó ti ọ̀run wá ju gbogbo ènìyàn lọ.
Read full chapter
Johanu 17:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 17:14
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
14 (A)Èmi ti fi ọ̀rọ̀ rẹ fún wọn; ayé sì ti kórìíra wọn, nítorí tí wọn kì í ṣe ti ayé, gẹ́gẹ́ bí èmi kì í ti í ṣe ti ayé.
Read full chapter
1 Johanu 4:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Johanu 4:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
5 (A)Tí ayé ni wọ́n, nítorí náà ni wọn ṣe ń sọ̀rọ̀ bí ẹni ti ayé, ayé sì ń gbọ́ tí wọn.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.