Font Size
Luku 2:36
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 2:36
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
36 (A)Ẹnìkan sì ń bẹ, Anna wòlíì, ọmọbìnrin Penueli, nínú ẹ̀yà Aṣeri: ọjọ́ ogbó rẹ̀ pọ̀, ó ti bá ọkọ gbé ní ọdún méje láti ìgbà wúńdíá rẹ̀ wá;
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 21:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 21:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 Ọkùnrin yìí sì ní ọmọbìnrin mẹ́rin, wúńdíá, tí wọ́n máa ń sọtẹ́lẹ̀.
Read full chapter
1 Kọrinti 14:34
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 14:34
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
34 (A)Jẹ́ ki àwọn obìnrin yín dákẹ́ nínú ìjọ: nítorí a kò fi fún wọn láti sọ̀rọ̀, ṣùgbọ́n jẹ́ kí wọn wà lábẹ́ ìtẹríba, gẹ́gẹ́ bí òfin pẹ̀lú ti wí.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.