Font Size
Gẹnẹsisi 15:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 15:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
6 (A)Abramu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.
Read full chapter
Isaiah 41:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Isaiah 41:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
8 (A)(B) “Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ Israẹli, ìránṣẹ́ mi,
Jakọbu, ẹni tí mo ti yàn,
ẹ̀yin ìran Abrahamu, ọ̀rẹ́ mi,
2 Kronika 20:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Kronika 20:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 (A)Ìwọ ha kọ́ Ọlọ́run wa, tí o ti lé àwọn olùgbé ilẹ̀ yìí jáde níwájú àwọn ènìyàn Israẹli, tí o sì fi fún irú-ọmọ Abrahamu ọ̀rẹ́ rẹ láéláé?
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.